2 Pétérù 3:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ẹ máa dàgbà nínú oore-ọ̀fẹ́ àti nínú ìmọ̀ Olúwa àti Olùgbàlà wa Jésù Kírísítì; ẹni tí ògo wà fún nísinsìn yìí àti títí láé. Àmín.

2 Pétérù 3

2 Pétérù 3:9-18