2 Pétérù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(nítorí ọkùnrin olóòótọ́ náà bí ó ti ń gbé àárin wọn, tí ó ń rí tí ó sì ń gbọ́, lójoojúmọ́ ni ìwà búburú wọn ń bá ọkàn òtítọ́ rẹ̀ jẹ́)

2 Pétérù 2

2 Pétérù 2:1-16