2 Pétérù 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínù ìwà wòbìà wọn, àwọn ẹlẹ́kọ̀-òdì wọ̀nyìí yóò máa reẹ ẹ yín jẹ́ nípa ìtàn àsán. Ìdájọ́ ẹni tí kò falẹ̀ láti ìgbà yìí wá àti ìparun wọn tí kò sí tòògbé.

2 Pétérù 2

2 Pétérù 2:1-7