2 Pétérù 2:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òwe òtítọ́ náà ṣẹ sí wọn lára: “Ajá tún padà sí èébì ara rẹ̀; àti ẹlẹ́dẹ̀ tí a ti wẹ̀ mọ́ tún padà ń yíràá nínú ẹrọ̀fọ̀.”

2 Pétérù 2

2 Pétérù 2:13-22