2 Pétérù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí oore-ọ̀fẹ́ àti àlàáfíà máa bí sí i fún yín nínú ìmọ̀ Ọlọ́run àti ti Jésù Olúwa wá.

2 Pétérù 1

2 Pétérù 1:1-6