2 Pétérù 1:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa pẹ̀lú sì gbọ́ ohun yìí tí ó ti ọ̀run wá nígbà tí àwa wà pẹ̀lú rẹ̀ ní orí òkè mímọ́ náà.

2 Pétérù 1

2 Pétérù 1:11-21