2 Ọba 9:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jórámù yípò padà, ó sì sá lọ ó sì ń pe Áhásáyà, “ó ṣe ìwà àrékérekè, Áhásáyà!”

2 Ọba 9

2 Ọba 9:16-25