2 Ọba 9:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìyẹn kì í ṣe òótọ́!” Wọ́n wí. “Ṣọ fún wa.”Jéhù wí, “Èyí ni ohun tí ó sọ fún mi: ‘Èyí ni ohun tí Olúwa wí: Èmi fi àmì òróró yàn ọ́ ní ọba lórí Ísírẹ́lì.’ ”

2 Ọba 9

2 Ọba 9:2-16