2 Ọba 9:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún Jésébélì, ajá ni yóò jẹ ẹ́ ní oko Jésírẹ́lì, kò sì sí ẹni tí yóò sin òkúrẹ̀.’ ” Nígbà náà ó sí ìlẹ̀kùn, ó sì sálọ.

2 Ọba 9

2 Ọba 9:4-12