2 Ọba 9:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wòlíì Èlíṣà fi àṣẹ pe ọkùnrin kan láti ẹgbẹ́ àwọn wòlíì, ó sì wí fún un pé, “Ki agbádá rẹ sínú ọ̀já àmùrè rẹ, gba ṣágo kékeré òróró yìí pẹ̀lú rẹ, kí o sì lọ sí Ramoti-Gílíádì.

2 Ọba 9

2 Ọba 9:1-8