2 Ọba 8:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhásáyà sì lọ pẹ̀lú Jórámù ọmọ Áhábù lọ sí ogun lórí Hásáélì ọba Árámù ní Ramoti-Gílíádì. Àwọn ará Ṣíríà ṣẹ́ Jórámù lẹ́sẹ̀.

2 Ọba 8

2 Ọba 8:23-29