2 Ọba 8:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhásáyà jẹ́ ẹni ọdún méjìlélógún nígbà tí ó di ọba. Ó sì jọba ní ọdún kan ní Jérúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ a sì máa jẹ́ Átalíàh, ọmọbìnrin Ómírìe ọba Ísírẹ́lì.

2 Ọba 8

2 Ọba 8:21-29