2 Ọba 8:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jórámù sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀ a sì sin ín pẹ̀lú wọn ní ìlú Dáfídì, Áhásáyà ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

2 Ọba 8

2 Ọba 8:14-28