2 Ọba 8:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíṣà da á lóhùn pé, “Lọ kí o lọ sọ fún un pé, ‘Ìwo ìbá sàn ní tòótọ́’; ṣùgbọ́n Olúwa ti fi hàn mí pé nítòotọ́ òun yóò kú.”

2 Ọba 8

2 Ọba 8:2-14