2 Ọba 7:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àfẹ̀mójúmọ́ wọ́n dìde wọ́n sì lọ sí ibùdó àwọn ará Síríà. Nígbà tí wọ́n dé ẹ̀gbẹ́ ibùdó náà, kò sí ọkùnrin kan níbẹ̀,

2 Ọba 7

2 Ọba 7:1-14