2 Ọba 7:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n yan kẹ̀kẹ́ méjì pẹ̀lú ẹsin wọn, ọba sì ránsẹ́ tọ ogun àwọn ará Síríà lẹ́yìn ó pàṣẹ fún àwọn awakọ̀ pé, “Ẹ lọ kí e lọ wo ohun tí ó ṣẹlẹ̀.”

2 Ọba 7

2 Ọba 7:12-19