2 Ọba 6:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí mú ọba Árámù bínú. Ó pe àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, ó sì béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “Ṣé ìwọ kò ní sọ fún un èwo nínú wa ni ó wà ní ẹ̀gbẹ́ ọba Ísírẹ́lì?”

2 Ọba 6

2 Ọba 6:9-16