2 Ọba 3:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lásìkò ìgbà yìí ọba Jéhórámù jáde kúrò ní Ṣamáríà ó sì yí gbogbo Ísírẹ́lì nípò padà.

2 Ọba 3

2 Ọba 3:2-7