2 Ọba 3:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíṣà wí pé, “Gẹ́gẹ́ bí ó ti wà pé Olúwa àwọn ọmọ ogun wà láyé, ẹni tí mo ń sìn tí èmi kò bá ní ọ̀wọ̀ fún ojú Jèhósáfátì ọba Júdà, Èmi kò ní wò ó tàbí èmi kì bá ti rí ọ.

2 Ọba 3

2 Ọba 3:7-23