2 Ọba 3:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jèhóṣáfátì wí pé, “ọ̀rọ̀ Olúwa wà pẹ̀lú rẹ̀.” Bẹ́ẹ̀ ni ọba Ísírẹ́lì àti Jèhóṣáfátì àti ọba Édómù sọ̀ kalẹ̀ tọ̀ ọ́ lọ.

2 Ọba 3

2 Ọba 3:4-22