2 Ọba 25:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nebukadínésárì ọba Bábílónì ó mú Gédalíàh ọmọ Áhíkámù ọmọ ṣáfánì, láti jọba lórí àwọn ènìyàn tí ó ti fa kalẹ̀ lẹ́yìn ní Júdà.

2 Ọba 25

2 Ọba 25:17-23