2 Ọba 24:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéhóíákínì jẹ́ ẹni ọdún méjìdínlógún nígbà tí ó di ọba, ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún oṣù mẹ́ta. Orúkọ ìyá a rẹ̀ a sì máa jẹ́ Néhúṣítà ọmọbìnrin Élínátanì; ó wá láti Jérúsálẹ́mù.

2 Ọba 24

2 Ọba 24:5-12