2 Ọba 24:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nebukadinéṣárì mú Jéhóíákínì ní ìgbékùn lọ sí Bábílónì. Ó sì tún mú ìyá ọba láti Jérúsálẹ́mù lọ sí Bábílónì, ìyàwó rẹ̀ àwọn ìjòyè rẹ̀ àti àwọn olórí ile náà.

2 Ọba 24

2 Ọba 24:5-20