2 Ọba 23:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò Nékó sì fi sí inú ìdè ní Ríbílà ní ilẹ̀ Hámátì, kí ó má ba à lè jọba ní Jérúsálẹ́mù. Ó sì tan Júdà jẹ fun iye ìwọ̀n ẹgbẹ̀rin talẹ́ntì wúrà kan.

2 Ọba 23

2 Ọba 23:26-37