2 Ọba 22:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún ọba Júdà tí ó rán yín láti bèrè lọ́wọ́ Olúwa, ‘Èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí nípa ọ̀rọ̀ wọ̀n-ọn-nì tí ìwọ ti gbọ́.

2 Ọba 22

2 Ọba 22:16-20