2 Ọba 22:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Èyí ni ohun tí Olúwa wí: Èmi yóò mú ibi wá sí ibí àti àwọn ènìyàn rẹ ní ìbámu pẹ̀lú gbogbo ohun tí a kọ sínú ìwé tí ọba Júdà ti kà.

2 Ọba 22

2 Ọba 22:8-17