2 Ọba 21:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó rìn ní gbogbo ọ̀nà baba rẹ̀: Ó sì ń sin àwọn ère tí baba rẹ̀ ń sìn, ó sì ń tẹrí rẹ̀ ba fún wọn.

2 Ọba 21

2 Ọba 21:13-25