2 Ọba 19:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa ṣọ nípa ti ọba Áṣíríà:“Kò ní wọ ìlú yìítàbí ta ọfà síbí.Kò ní wá níwájú rẹ pẹ̀lúàpáta tàbí kó ìdọ̀tí àgbò sí ọ̀kánkán rẹ.

2 Ọba 19

2 Ọba 19:24-37