2 Ọba 19:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ́ọ̀tọ́ ìwọ ti gbọ́ gbogbo ohun tí ọba Ásíríà tí ó ṣe sí gbogbo àwọn ìlú, ó pa wọ́n run pátapáta. Ìwọ yóò sì gbàlà?

2 Ọba 19

2 Ọba 19:5-15