2 Ọba 18:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọdún kẹrin ọba Heṣekáyà, nígbà tí ó jẹ́ ọdún keje Hóséà ọmọ Élà ọba Ísírẹ́lì. Ṣálímánésérì ọba Áṣíríà yàn lára Ṣamáríà ó sì tẹ̀dó tì í.

2 Ọba 18

2 Ọba 18:5-14