2 Ọba 18:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Heṣekáyà sì gbẹ́kẹ̀lé Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì. Kò sì sí ẹnìkan tí ó dàbí tirẹ̀ lára gbogbo àwọn ọba Júdà, bóyá kí ó tó jẹ tàbí lẹ́yìn rẹ̀.

2 Ọba 18

2 Ọba 18:2-15