2 Ọba 18:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbo ni àwọn òrìṣà Hámátì àti Árípádì gbé wà? Níbo ni àwọn òrìṣà Ṣérárifáímù, Hẹ́nà àti ífà gbé wà? Wọ́n ha gba Ṣámáríà kúrò lọ́wọ́ mi bí?

2 Ọba 18

2 Ọba 18:27-37