2 Ọba 18:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ wí pé ìwọ ni ẹ̀tà àti ti ogun alágbára ṣùgbọ́n ìwọ sọ̀rọ̀ òfìfo nìkan, lórí ta ni ìwọ gbẹ́kẹ̀ rẹ lé tí ìwọ fi ń ṣe ọ̀tẹ̀ sí mi?

2 Ọba 18

2 Ọba 18:11-22