2 Ọba 18:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Áṣíríà lé Ísírẹ́lì kúrò ní Áṣíríà, wọ́n sì ṣe àtìpó wọn ní Hálà, ní Gósánì létí odò Hábórì àti ní ìlú àwọn ará Médíà.

2 Ọba 18

2 Ọba 18:8-12