2 Ọba 17:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe búburú ní ojú Olúwa, ṣùgbọ́n kì í ṣe bí i ti ọba Ísírẹ́lì ẹni tí ó ti wà ṣáájú rẹ̀.

2 Ọba 17

2 Ọba 17:1-12