2 Ọba 16:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ìyókù ìṣe Áhásì tí ó ṣe, a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba Júdà?

2 Ọba 16

2 Ọba 16:17-20