2 Ọba 15:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jótamù sinmi pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀. A sì sin ín pẹ̀lú wọn ní ìlú ńlá Dáfídì, ìlú ńlá ti baba rẹ̀. Áhásì ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.

2 Ọba 15

2 Ọba 15:33-38