2 Ọba 15:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣálúmù ọmọ Jábésì di ọba ní ọdún kọkàndínlógójì Ùsáyà ọba Júdà, ó sì jọba ní Ṣamáríà fún oṣù kan.

2 Ọba 15

2 Ọba 15:7-15