2 Ọba 15:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣálúmù ọmọ Jábésì dìtẹ̀ sí Ṣakaríà. Ó dojúkọ ọ́ níwájú àwọn ènìyàn, ó sì pa á, ó sì jọba dípò rẹ̀.

2 Ọba 15

2 Ọba 15:5-14