2 Ọba 14:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Olúwa, ṣùgbọ́n kì í ṣe bí i Dáfídì baba a rẹ̀ tí ṣe. Nínú ohun gbogbo, ó tẹ́lé àpẹrẹ baba a rẹ̀ Jóásì.

2 Ọba 14

2 Ọba 14:1-13