2 Ọba 14:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéróbóámù sinmi pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, àwọn ọba Ísírẹ́lì Ṣekaríyà ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.

2 Ọba 14

2 Ọba 14:22-29