2 Ọba 14:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọdún kẹẹ̀dógún tí Ámásáyà ọmọ Jóásì ọba Júdà, Jéróbóámù ọmọ Jéhóásì ọba Ísírẹ́lì di ọba ní Ṣamáríà, ó sì jọba fún ọ̀kànlélógójì ọdún.

2 Ọba 14

2 Ọba 14:15-29