2 Ọba 13:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà Jéhóáhásì kígbe ó wá ojú rere Olúwa, Olúwa sì tẹ́tí sí i. Nítorí ó rí bí ọba Ṣíríà ti ń ni Ísírẹ́lì lára gidigidi.

2 Ọba 13

2 Ọba 13:1-11