2 Ọba 13:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ṣe búburú ní ojú Olúwa, kò sì yípadà kúrò nínú ọ̀kankan nínú ẹ̀ṣẹ̀ Jéróbóámù ọmọ Nébátì èyí tí ó ti ti Ísírẹ́lì láti fà. Ó sì tẹ̀síwájú nínú wọn.

2 Ọba 13

2 Ọba 13:9-13