2 Ọba 12:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóásì ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Olúwa ní gbogbo ọdún tí Jéhóíádà àlùfáà fi àsẹ fún un.

2 Ọba 12

2 Ọba 12:1-10