2 Ọba 12:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní déédéé àkókò yìí, Hásáélì ọba Ṣíríà gòkè lọ láti dojúkọ Gátì àti láti fi agbára mú un. Nígbà náà, ó yípadà láti dójukọ Jérúsálẹ́mù.

2 Ọba 12

2 Ọba 12:13-21