2 Ọba 11:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ẹ̀yin tí ó wà ní ẹgbẹ́ kejì yóòkù tí kì í lọ ibi iṣẹ́ ìsìn ní ọjọ́ ìsinmi gbogbo ni kí ó ṣọ́ ilé tí a kọ́ fún Olúwa fún ọba.

2 Ọba 11

2 Ọba 11:5-12