2 Ọba 11:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó pàṣẹ fún wọn, wí pé, “Ìwọ tí ó wà nínú àwọn ẹgbẹ́ mẹ́tẹ̀ta tí ó ń lọ fún iṣẹ́ ìsìn ní ọjọ́ ìsinmi—ìdámẹ́ta yín fún síṣọ́ ààfin ọba.

2 Ọba 11

2 Ọba 11:1-15