2 Ọba 11:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn olùṣọ́, olúkúlùkù pẹ̀lú ohun ìjà rẹ̀ ní ọwọ́ rẹ̀, wọ́n sì dúró ṣinṣin yìí ọba ká—lẹ́báá pẹpẹ àti ilé ìhà gúsù sí ìhà àríwá ilé tí a kọ́ fun Olúwa náà.

2 Ọba 11

2 Ọba 11:1-14