2 Ọba 10:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéhù sì sọ fún olùṣọ́ pé, “Kí ó mú aṣọ ìgúnwà wá fún gbogbo àwọn òjíṣẹ́ Báálì.” Bẹ́ẹ̀ ni ó mú aṣọ ìgúnwà jáde wá fún wọn.

2 Ọba 10

2 Ọba 10:17-23